Ominira


Owa iya iyé é a, owa iya iyé é a
Owa iya iyé é a
Owa iya iyé é a, owa iya iyé é a
Owa iya iyé é a

Onikaloukou wa n'fè ri ominira
Onikaloukou wa n'fè aseyori
Onikaloukou wa n'fè ri oyaya
Onikaloukou fèlo wa idaji
Mmm ewa ka lo

Ka lo fè wa tchitchè kori ominira
N'tori ominira toro ishè gan
Edahoun gbogbo yin foun ominira

Aaah ominira, foun min l'owo ka man
Lo ominira
Aaah ominira, foun min l'owo ka man
Lo ominira

Owa iya iyé é a, owa iya iyé é a
Owa iya iyé é a
Owa iya iyé é a, owa iya iyé é a
Owa iya iyé é a

Onikaloukou wa n'fè ri ominira
Onikaloukou wa n'fè aséyori
Onikaloukou wa n'fè ri oyaya
Onikaloukou fèlo wa idaji

Ayé wa toro kawa ri ominira
Ayé wa fè dada foun gbogbo èniyan
Ayé sin wa lodo ominira
Mmm ewa ka lo

Aaah ominira, foun min l'owo ka man
Lo ominira
Aaah ominira, foun min l'owo ka man
Lo ominira

Onikaloukou wa n'fè ri ominira
Onikaloukou wa n'fè aséyori
Onikaloukou wa n'fè ri oyaya
Onikaloukou fèlo wa idaji

Ayé wa toro kawa ri ominira
Ayé wa fè dada foun gbogbo èniyan
Ayé sin wa lodo ominira
Mmm ewa ka lo a

Aaah ominira, foun min l'owo ka man
Lo ominira
Aaah ominira, foun min l'owo ka man
Lo ominira

Aaah ominira
Lo, ominira
Aaah ominira
Lo, ominira

Aaah ominira
Lo, ominira
Aaah ominira
Lo, ominira

Aaah ominira
Lo, ominira

Aaah ominira, foun min l'owo ka man
Lo ominira
Aaah ominira, foun min l'owo ka man
Lo ominira







Captcha
The Angelique Kidjo Ominira are brought to you by Lyrics-Keeper. You can use lyrics widget for karaoke. We tried to make lyrics as correct as possible, however if you have any corrections for Ominira lyrics, please feel free to submit them to us. If you want to download this song in mp3 you can visit one of our music sponsors.